Ìwé Òwe 5:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọmọ mi fetí sí ọgbọ́n tí mò ń kọ́ ọ,tẹ́tí rẹ sí òye mi,

2. kí o baà lè ní làákàyè,kí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ lè kún fún ìmọ̀.

3. Nítorí ẹnu alágbèrè obinrin a máa dùn bí oyin,ọ̀rọ̀ rẹ̀ sì tuni lára ju òróró lọ,

Ìwé Òwe 5