Ìwé Òwe 4:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí o bá fẹ́ gbọ́n, bẹ̀rẹ̀ sí kọ́gbọ́n,ohun yòówù tí o lè tún ní,ọgbọ́n ló jù, nítorí náà jẹ́ ọlọ́gbọ́n.

Ìwé Òwe 4

Ìwé Òwe 4:5-14