Ìwé Òwe 31:2-4 BIBELI MIMỌ (BM)

2. Ìwọ ni ọmọ mi, ọmọ bíbí inú mi,ìwọ ni ọmọ tí mo jẹ́jẹ̀ẹ́ bí.

3. Má ṣe lo agbára rẹ lórí obinrin,má fi ọ̀nà rẹ lé àwọn tí wọn ń pa ọba run lọ́wọ́.

4. Gbọ́, ìwọ Lemueli,ọba kò gbọdọ̀ máa mu ọtí,àwọn aláṣẹ kò sì gbọdọ̀ máa wá ọtí líle.

Ìwé Òwe 31