Ìwé Òwe 3:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Má sọ fún aládùúgbò rẹ pé,“Máa lọ ná, n óo fún ọ tí o bá pada wá lọ́la,”nígbà tí ohun tí ó fẹ́ wà lọ́dọ̀ rẹ.

Ìwé Òwe 3

Ìwé Òwe 3:27-33