Ìwé Òwe 29:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọ́gbọ́n ọmọ a máa mú inú baba rẹ̀ dùn,ṣugbọn ẹni tí ń tẹ̀lé aṣẹ́wó kiri, ń fi ọrọ̀ ara rẹ̀ ṣòfò.

Ìwé Òwe 29

Ìwé Òwe 29:1-11