Ìwé Òwe 28:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Òye ìdájọ́ òdodo kò yé àwọn eniyan burúkú,ṣugbọn ó yé àwọn tí ń wá OLUWA yékéyéké.

Ìwé Òwe 28

Ìwé Òwe 28:3-9