Ìwé Òwe 25:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Má fi ìwàǹwára fa ẹnikẹ́ni lọ sílé ẹjọ́,nítorí kí ni o óo ṣe nígbà tí aládùúgbò rẹ bá dójútì ọ́.

Ìwé Òwe 25

Ìwé Òwe 25:7-12