Ìwé Òwe 24:33-34 BIBELI MIMỌ (BM)

33. Oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀,ìkáwọ́ gbera díẹ̀ láti sinmi,

34. bẹ́ẹ̀ ni òṣì yóo ṣe dé bá ọbíi kí olè yọ sí eniyan,àìní yóo sì wọlé tọ̀ ọ́ bí ẹni tí ó di ihamọra ogun.

Ìwé Òwe 24