Ìwé Òwe 23:18-20 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Dájúdájú, ọjọ́ ọ̀la rẹ yóo dára,ìrètí rẹ náà kò sì ní já sí òfo.

19. Fetí sí mi, ọmọ mi, kí o sì gbọ́n,darí ọkàn rẹ sí ọ̀nà títọ́.

20. Má bá àwọn ọ̀mùtí kẹ́gbẹ́;tabi àwọn wọ̀bìà, tí wọn ń jẹ ẹran ní àjẹkì;

Ìwé Òwe 23