Ìwé Òwe 21:30-31 BIBELI MIMỌ (BM)

30. Kò sí ọgbọ́n, tabi òye, tabi ìmọ̀,tí ó lè dojú kọ OLUWA kí ó mókè.

31. Eniyan a máa tọ́jú ẹṣin sílẹ̀ de ọjọ́ ogun,ṣugbọn OLUWA ló ni ìṣẹ́gun.

Ìwé Òwe 21