Ìwé Òwe 21:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibi ni ọkàn eniyan burúkú máa ń fẹ́,àwọn aládùúgbò rẹ̀ kì í sìí rí ojurere rẹ̀.

Ìwé Òwe 21

Ìwé Òwe 21:9-13