Ìwé Òwe 21:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Orísun omi ni ọkàn ọba lọ́wọ́ OLUWA,ibi tí ó bá wu Oluwa ni ó ń darí rẹ̀ sí.

2. Gbogbo ọ̀nà eniyan ni ó dára lójú ara rẹ̀,ṣugbọn ọkàn ni OLUWA ń wò.

Ìwé Òwe 21