Ìwé Òwe 2:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọmọ mi, bí o bá gba ọ̀rọ̀ mi,tí o sì pa òfin mi mọ́,

2. tí o bá ń tẹ́tí rẹ sílẹ̀ sí ọgbọ́n,tí o sì fi ọkàn sí òye,

Ìwé Òwe 2