Ìwé Òwe 16:32-33 BIBELI MIMỌ (BM)

32. Ẹni tí kì í tètè bínú sàn ju alágbára lọ,ẹni tí ń kó ara rẹ̀ níjàánu sàn ju ẹni tí ó jagun gba odidi ìlú lọ.

33. À máa ṣẹ́ gègé kí á lè mọ ìdí ọ̀ràn,ṣugbọn OLUWA nìkan ló lè pinnu ohunkohun.

Ìwé Òwe 16