Ìwé Òwe 14:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọ́gbọ́n a máa ṣọ́ra, a sì máa sá fún ibi,ṣugbọn òmùgọ̀ kì í rọra ṣe, kì í sì í bìkítà.

Ìwé Òwe 14

Ìwé Òwe 14:8-25