Ìwé Òwe 13:23-25 BIBELI MIMỌ (BM) Oko tí talaka dá lè mú ọpọlọpọ oúnjẹ jáde,ṣugbọn àwọn alaiṣootọ níí kó gbogbo rẹ̀ lọ.