Ìwé Òwe 11:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA kórìíra òṣùnwọ̀n èké,òṣùnwọ̀n tí ó péye ni inú rẹ̀ dùn sí.

2. Bí ìgbéraga bá wọlé, àbùkù a tẹ̀lé e,ṣugbọn ọgbọ́n wà pẹlu àwọn onírẹ̀lẹ̀.

3. Òtítọ́ inú àwọn olódodo a máa tọ́ wọn,ṣugbọn ìwà aiṣootọ àwọn ọ̀dàlẹ̀ níí pa wọ́n.

Ìwé Òwe 11