Ìwé Òwe 11:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA kórìíra òṣùnwọ̀n èké,òṣùnwọ̀n tí ó péye ni inú rẹ̀ dùn sí.

2. Bí ìgbéraga bá wọlé, àbùkù a tẹ̀lé e,ṣugbọn ọgbọ́n wà pẹlu àwọn onírẹ̀lẹ̀.

Ìwé Òwe 11