Ìwé Òwe 10:30-32 BIBELI MIMỌ (BM)

30. Gbọningbọnin ni olódodo yóo dúró,ṣugbọn ẹni ibi kò ní lè gbé ilẹ̀ náà.

31. Ẹnu olódodo kún fún ọ̀rọ̀ ọgbọ́n,ṣugbọn ẹnu alaiṣootọ ni a pamọ́.

32. Olódodo mọ ohun tí ó dára láti sọ,ṣugbọn ti eniyan burúkú kò ju ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn lọ.

Ìwé Òwe 10