Ìwé Òwe 1:5-7 BIBELI MIMỌ (BM)

5. kí ọlọ́gbọ́n lè gbọ́, kí ó sì fi ìmọ̀ kún ìmọ̀ rẹ̀,kí ẹni tí ó ní òye lè ní ìmọ̀ pẹlu.

6. Láti lè mọ òwe ati àkàwé ọ̀rọ̀,ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n ati àdììtú ọ̀rọ̀.

7. Ìbẹ̀rù OLUWA ni ìbẹ̀rẹ̀ ìmọ̀,ṣugbọn àwọn òmùgọ̀ a máa pẹ̀gàn ọgbọ́n ati ẹ̀kọ́.

Ìwé Òwe 1