Ìwé Oníwàásù 5:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó! Ohun tí mo rí pé ó dára jù, tí ó sì yẹ, ni pé kí eniyan jẹ, kí ó mu, kí ó sì gbádùn gbogbo làálàá tí ó ń ṣe láyé, ní ìwọ̀nba ọjọ́ tí Ọlọrun fún un, nítorí èyí ni ìpín rẹ̀.

Ìwé Oníwàásù 5

Ìwé Oníwàásù 5:15-20