Ìwé Oníwàásù 4:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ọ̀kan bá ṣubú,ekeji yóo gbé e dìde.Ṣugbọn ẹni tí ó dá wà gbé!Nítorí nígbà tí ó bá ṣubúkò ní sí ẹni tí yóo gbé e dìde.

Ìwé Oníwàásù 4

Ìwé Oníwàásù 4:2-16