Ìwé Oníwàásù 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àkókò fífa nǹkan ya wà, àkókò rírán nǹkan pọ̀ sì wà;àkókò dídákẹ́ wà, àkókò ọ̀rọ̀ sísọ sì wà.

Ìwé Oníwàásù 3

Ìwé Oníwàásù 3:1-13