Ìwé Oníwàásù 3:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibìkan náà ni gbogbo wọn ń lọ; inú erùpẹ̀ ni gbogbo wọn ti wá, inú erùpẹ̀ ni wọn yóo sì pada sí.

Ìwé Oníwàásù 3

Ìwé Oníwàásù 3:11-22