Ìwé Oníwàásù 3:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohunkohun tí ó wà, ó ti wà tẹ́lẹ̀, èyí tí yóo sì tún wà, òun pàápàá ti wà rí; Ọlọrun yóo ṣe ìwádìí gbogbo ohun tí ó ti kọjá.

Ìwé Oníwàásù 3

Ìwé Oníwàásù 3:6-22