Ìwé Oníwàásù 10:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Òmùgọ̀ ń sọ̀rọ̀ láìdákẹ́,kò sí ẹni tí ó mọ ohun tí ń bọ̀ lẹ́yìn ọ̀la,ta ni lè sọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn rẹ̀ fún un.

Ìwé Oníwàásù 10

Ìwé Oníwàásù 10:8-20