Isikiẹli 7:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo fọn fèrè ogun, wọn óo múra ogun, ṣugbọn ẹnikẹ́ni kò ní jáde lọ sójú ogun nítorí ibinu mi ti dé sórí gbogbo wọn.

Isikiẹli 7

Isikiẹli 7:6-23