Isikiẹli 44:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo wé lawani tí a fi aṣọ funfun rán, wọn yóo sì wọ ṣòkòtò aṣọ funfun. Wọn kò gbọdọ̀ fi ohunkohun tí ń mú kí ooru mú eniyan di ara wọn ní àmùrè.

Isikiẹli 44

Isikiẹli 44:16-24