Isikiẹli 44:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà ó mú mi wá sí ẹnu ọ̀nà ìta ibi mímọ́ tí ó kọjú sí ìlà oòrùn, ìlẹ̀kùn ẹnu ọ̀nà náà wà ní títì.

Isikiẹli 44

Isikiẹli 44:1-2