Isikiẹli 41:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó wọn Tẹmpili, ó gùn ní ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 45). Àgbàlá ati ilé náà pẹlu ògiri rẹ̀ gùn ní ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 45).

Isikiẹli 41

Isikiẹli 41:9-22