Isikiẹli 40:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó mú mi lọ sí ìhà ìlà oòrùn gbọ̀ngàn inú, ó sì wọn ẹnu ọ̀nà rẹ̀, bákan náà ni ó rí pẹlu àwọn yòókù.

Isikiẹli 40

Isikiẹli 40:23-38