Isikiẹli 4:17 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo ṣe bẹ́ẹ̀ kí wọ́n lè ṣe aláìní oúnjẹ ati omi, kí wọ́n lè máa wo ara wọn pẹlu ìpayà, kí wọ́n sì parun nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.”

Isikiẹli 4

Isikiẹli 4:14-17