Isikiẹli 36:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fọ́n wọn ká sáàrin àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, wọ́n sì tú káàkiri orí ilẹ̀ ayé. Ìwà ati ìṣe wọn ni mo fi dá wọn lẹ́jọ́.

Isikiẹli 36

Isikiẹli 36:10-21