Isikiẹli 3:17 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọmọ eniyan, mo ti fi ọ́ ṣe olùṣọ́ fún ilé Israẹli. Nígbàkúùgbà tí o bá gbọ́ ohunkohun lẹ́nu mi, o gbọdọ̀ kìlọ̀ fún wọn.

Isikiẹli 3

Isikiẹli 3:7-24