Isikiẹli 27:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Didani ń bá ọ ṣòwò, ọpọlọpọ etíkun ni ẹ tí ń tajà, wọ́n ń fi eyín erin ati igi Ẹboni ṣe pàṣípààrọ̀ fún ọ.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:9-25