Isikiẹli 26:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo fi pátákò ẹsẹ̀ àwọn ẹṣin rẹ̀ tú gbogbo ilẹ̀ ìgboro rẹ, yóo fi idà pa àwọn eniyan rẹ; yóo sì wó àwọn òpó ńláńlá rẹ lulẹ̀.

Isikiẹli 26

Isikiẹli 26:3-16