Isikiẹli 18:8 BIBELI MIMỌ (BM)

tí kò gba owó èlé lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni, tí ó yàgò fún ẹ̀ṣẹ̀, tí ó ń dá ẹjọ́ ẹ̀tọ́ láàrin ẹni meji,

Isikiẹli 18

Isikiẹli 18:1-13