Isikiẹli 10:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìhà gúsù ilé náà ni àwọn Kerubu dúró sí nígbà tí ọkunrin náà wọlé, ìkùukùu sì bo àgbàlá ààrin ilé náà.

Isikiẹli 10

Isikiẹli 10:1-5