Isikiẹli 10:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ní iwájú mẹrin mẹrin ati ìyẹ́ mẹrin mẹrin, wọ́n sì ní ọwọ́ bí ọwọ́ eniyan lábẹ́ ìyẹ́ wọn.

Isikiẹli 10

Isikiẹli 10:18-22