Ìfihàn 9:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Agbára àwọn ẹṣin wọnyi wà ní ẹnu wọn ati ní ìrù wọn. Nítorí ìrù wọn dàbí ejò, wọ́n ní orí. Òun sì ni wọ́n fi ń ṣe àwọn eniyan léṣe.

Ìfihàn 9

Ìfihàn 9:10-21