Ìfihàn 18:13 BIBELI MIMỌ (BM)

oríṣìíríṣìí òróró ìkunra, turari ati òjíá, ọtí, òróró olifi, ọkà, ati àgbàdo, ẹṣin, kẹ̀kẹ́ ogun, ẹrú, àní ẹ̀mí eniyan.

Ìfihàn 18

Ìfihàn 18:9-15