Ìfihàn 16:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli keje da ohun tí ó wà ninu àwo rẹ̀ sinu afẹ́fẹ́. Ẹnìkan bá fi ohùn líle sọ̀rọ̀ láti ibi ìtẹ́ tí ó wà ninu Tẹmpili, ó ní, “Ó ti parí!”

Ìfihàn 16

Ìfihàn 16:10-21