Ìfihàn 15:3 BIBELI MIMỌ (BM)

wọ́n ń kọ orin Mose iranṣẹ Ọlọrun ati orin Ọ̀dọ́ Aguntan náà pé,“Iṣẹ́ ńlá ati iṣẹ́ ìyanu ni iṣẹ́ rẹ,Oluwa, Ọlọrun Olodumare.Òdodo ati òtítọ́ ni àwọn iṣẹ́ ọnà rẹ,Ọba àwọn orílẹ̀-èdè.

Ìfihàn 15

Ìfihàn 15:1-8