Ìṣe Àwọn Aposteli 8:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwẹ̀fà náà sọ fún Filipi pé, “Mo bẹ̀ ọ́, ọ̀rọ̀ ta ni wolii Ọlọrun yìí ń sọ, ọ̀rọ̀ ara rẹ̀ ni tabi ọ̀rọ̀ ẹlòmíràn?”

Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:26-40