Ìṣe Àwọn Aposteli 8:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn aposteli tí ó wà ní Jerusalẹmu gbọ́ bí àwọn ará Samaria ti gba ọ̀rọ̀ Ọlọrun. Wọ́n bá rán Peteru ati Johanu sí wọn.

Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:10-17