Ìṣe Àwọn Aposteli 7:56 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá dáhùn pé, “Ẹ wò ó, mo rí ojú ọ̀run tí ó pínyà. Mo wá rí Ọmọ-Eniyan tí ó dúró lọ́wọ́ ọ̀tún Ọlọrun.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:50-60