Ìṣe Àwọn Aposteli 7:48-50 BIBELI MIMỌ (BM)

48. “Bẹ́ẹ̀ ni Ọba tí ó ga jùlọ kì í gbé ilé tí a fi ọwọ́ kọ́. Gẹ́gẹ́ bí wolii nì ti sọ:

49. ‘Ọ̀run ni ìtẹ́ mi, ayé ni tìmùtìmù ìtìsẹ̀ mi.Irú ilé wo ni ẹ̀ báà kọ́ fún mi?Bẹ́ẹ̀ ni Oluwa wí.Níbo ni ẹ̀ báà palẹ̀ mọ́ fún mi pé kí n ti máa sinmi?

50. Ṣebí èmi ni mo fọwọ́ mi ṣe gbogbo nǹkan wọnyi?’

Ìṣe Àwọn Aposteli 7