Ìṣe Àwọn Aposteli 7:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose yìí ni ó sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, ‘Ọlọrun yóo gbé wolii kan bí èmi dìde fun yín láàrin àwọn arakunrin yín.’

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:31-39