Ìṣe Àwọn Aposteli 7:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá rí ọ̀kan ninu àwọn ará rẹ̀ tí ará Ijipti ń jẹ níyà. Ó bá lọ gbà á sílẹ̀. Ó gbẹ̀san ìyà tí wọ́n ti fi jẹ ẹ́, ó lu ará Ijipti náà pa.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:20-26