Ìṣe Àwọn Aposteli 7:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Stefanu bá tẹnu bọ̀rọ̀, ó ní, “Ẹ̀yin arakunrin ati baba mi, ẹ gbọ́ ohun tí mo ní sọ. Ọlọrun Ológo farahàn fún baba wa, Abrahamu, nígbà tí ó ṣì wà ní ilẹ̀ Mesopotamia, kí ó tó wá máa gbé ilẹ̀ Kenaani.

Ìṣe Àwọn Aposteli 7

Ìṣe Àwọn Aposteli 7:1-5